ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 8
  • December 4-10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 4-10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 8

December 4-10

JÓÒBÙ 22-24

  • Orin 49 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ṣé Èèyàn Wúlò fún Ọlọ́run?”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 23:13—Báwo ni àpẹẹrẹ Jèhófà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ kọ́wọ́ wa lè tẹ àwọn ohun tá a pinnu láti ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀? (w04 7/15 21-22)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 22:​1-22 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Àsọyé: (5 min.) w21.05 18-19 ¶17-20—Àkòrí: Jèhófà Máa Lò Wá Tá Ò Bá Jẹ́ Kó Sú Wa. (th ẹ̀kọ́ 20)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 134

  • “Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Múnú Jèhófà Dùn”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò.

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 3 ¶1-3, àwọn àpótí tó wà lójú ìwé 23, 24, 25, 26, àti 27

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 25 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́