ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 January ojú ìwé 10
  • February 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 January ojú ìwé 10

FEBRUARY 5-11

SÁÀMÙ 1-4

Orin 150 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Fara Mọ́ Ìjọba Ọlọ́run

(10 min.)

[Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù.]

Àwọn aláṣẹ ayé ti sọ ara wọn di ọ̀tá Ìjọba Ọlọ́run (Sm 2:2; w21.09 15 ¶8)

Jèhófà ń fún gbogbo èèyàn láǹfààní láti pinnu bóyá wọ́n máa fara mọ́ Ìjọba rẹ̀ (Sm 2:10-12)

Àwòrán: 1. Àwọn èèyàn tínú ń bí gbé àkọlé gàdàgbà dání, wọ́n sì ń wọ́de. 2. Ọkùnrin kan gbé àsíá dání, ó sì ń pariwo níbi eré ìdárayá kan. 3. Ọmọ ilé ìwé kan ń ka ẹ̀jẹ́ orílẹ̀-èdè. 4. Sójà kan gbé ìbọn arọ̀jò-ọta dání. 5. Àwọn olóṣèlú méjì ń ṣe ìkéde. 6. Obìnrin kan ń dìbò.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo ti pinnu pé mi ò ní dá sí ọ̀rọ̀ òṣèlú lọ́nàkọnà, kódà tíyẹn bá máa mú kí nǹkan nira fún mi?’—w16.04 24 ¶11.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 1:4—Báwo làwọn èèyàn burúkú ṣe dà bí “ìyàngbò tí afẹ́fẹ́ ń gbá lọ”? (it-1 425)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 3:1–4:8 (th ẹ̀kọ́ 12)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Máa Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Ẹ Wẹ́rẹ́—Ohun Tí Fílípì Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 1-2.

5. Máa Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Ẹ Wẹ́rẹ́—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Fílípì

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 3-5 àti apá “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 32

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 5 ¶9-15, àpótí tó wà lójú ìwé 41

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 61 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́