ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 March ojú ìwé 4
  • March 11-17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 11-17
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 March ojú ìwé 4

MARCH 11-17

SÁÀMÙ 18

Orin 148 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Jèhófà Ni . . . Ẹni Tó Ń Gbà Mí Sílẹ̀”

(10 min.)

Jèhófà ni àpáta gàǹgà, odi ààbò àti apata wa (Sm 18:1, 2; w09 5/1 14 ¶3-4)

Jèhófà máa ń gbọ́ tá a bá ké pè é fún ìrànlọ́wọ́ (Sm 18:6; it-2 1161 ¶7)

Jèhófà máa ń ràn wá lọ́wọ́ (Sm 18:16, 17; w22.04 3 ¶1)

Àwòrán: Dáfídì jókòó, ó ń yáná, ó sì ń rónú lórí onírúurú ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà ràn án lọ́wọ́. 1. Ó bá bíárì jà. 2. Ó kúnlẹ̀ sẹ́gbẹ̀ẹ́ kìnnìún tó ti kú. 3. Ó mú idà dání, ó sì gbẹ́sẹ̀ lé Gòláyátì tó dojú bolè.

Jèhófà lè pinnu láti yanjú àwọn ìṣòro kan tá a ní bó ṣe ṣe fún Dáfídì. Àmọ́ lọ́pọ̀ ìgbà, ó máa ń “ṣe ọ̀nà àbáyọ” ní ti pé ó máa ń fún wa lóhun tá a nílò ká lè fara da ìṣòro wa, ká má sì bọ́hùn.—1Kọ 10:13.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 18:10—Kí nìdí tí onísáàmù náà fi sọ pé Jèhófà gun kérúbù? (it-1 432 ¶2)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 18:20-39 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Jẹ́ Onínúure—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 1-2.

5. Jẹ́ Onínúure—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 3-5 àti “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 60

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(5 min.)

7. Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March

(10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà.

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 7 ¶1-8, àpótí ojú ìwé 53

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 69 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́