ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 July ojú ìwé 12
  • August 12-18

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 12-18
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 July ojú ìwé 12

AUGUST 12-18

SÁÀMÙ 73-74

Orin 36 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Kí La Lè Ṣe Tá Ò Fi Ní Máa Jowú Àwọn Tí Ò Sin Jèhófà?

(10 min.)

Tá ò bá kíyè sára, a lè máa jowú àwọn tí ò sin Ọlọ́run (Sm 73:3-5; w20.12 19 ¶14)

Dípò ká ya ara wa sọ́tọ̀, ṣe ló yẹ ká dara pọ̀ mọ́ àwọn ará wa láti jọ́sìn Jèhófà, ìyẹn á jẹ́ ká lè ní èrò tó tọ́ (Sm 73:17; Owe 18:1; w20.12 19 ¶15-16)

“Orí ilẹ̀ tó ń yọ̀” làwọn tí ò sin Jèhófà wà, àmọ́ àwọn tó ń sin Jèhófà máa “wọnú ògo” (Sm 73:18, 19, 24; w14 4/15 4 ¶5; w13 2/15 25-26 ¶3-5)

Ọ̀dọ́bìnrin Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ń wo àwọn ọmọléèwé ẹ̀ bí wọ́n ṣe ń gbádùn ara wọn, tí wọ́n ń sọ̀rọ̀ tí wọ́n sì ń tẹ fóònù, ó wá ń jowú wọn.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 74:13, 14—Kí ni “Léfíátánì” ṣàpẹẹrẹ? (it-2 240)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 74:1-23 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Lo àǹfààní tó bá yọ láti sọ fún ẹnì kan tó o mọ̀ nípa ohun tó o kọ́ nípàdé láìpẹ́ yìí. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 4)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì han ẹni náà. (lmd ẹ̀kọ́ 8 kókó 3)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(5 min.) Àsọyé. ijwbq 89—Àkòrí: Ṣé Gbogbo Ìsìn Ló Dáa? (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 72

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 14 ¶1-6, àpótí ojú ìwé 112

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 98 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́