ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 September ojú ìwé 6-7
  • September 23-29

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 23-29
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 September ojú ìwé 6-7

SEPTEMBER 23-29

SÁÀMÙ 88-89

Orin 22 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Ìṣàkóso Jèhófà Ló Dáa Jù

(10 min.)

Ìṣàkóso Jèhófà máa mú ìdájọ́ òdodo wá (Sm 89:14; w17.06 28 ¶5)

Ìṣàkóso Jèhófà máa mú káwọn èèyàn láyọ̀ (Sm 89:15, 16; w17.06 29 ¶10-11)

Ìṣàkóso Jèhófà máa wà títí láé (Sm 89: 34-37; w14 10/15 10 ¶14)

Àwòrán: Arákùnrin kan ń ronú lórí bí ìṣàkóso Jèhófà ṣe yàtọ̀ pátápátá sí tàwọn èèyàn. 1. Àwọn èèyàn ń bá ara wọn jiyàn níbi tí wọ́n ti ń ṣe ìwọ́de òṣèlú. 2. Àwọn ará ń kí ara wọn tẹ̀rín-tọ̀yàyà nípàdé.

Tá a bá ń ronú lórí bí ìṣàkóso Jèhófà ṣe dáa tó, ìyẹn ò ní jẹ́ ká dá sí ọ̀rọ̀ òṣèlú

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 89:37 —Kí ni ìyàtọ̀ tó wà láàárín bí òṣùpá ṣe jẹ́ adúróṣinṣin àti bí àwa èèyàn ṣe lè jẹ́ adúróṣinṣin? (cl 281 ¶4-5)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 89:1-24 (th ẹ̀kọ́ 11)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni tí kì í ṣe Kristẹni. (lmd ẹ̀kọ́ 5 kókó 5)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án. (th ẹ̀kọ́ 9)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(5 min.) Àsọyé. ijwbq 181—Àkòrí: Kí Ni Bíbélì Dá Lé? (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 94

7. Àwọn Ìlànà Jèhófà Ló Dáa Jù

(10 min.) Ìjíròrò.

Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń wo ìlànà Bíbélì nípa ìbálòpọ̀ àti ìgbéyàwó bí ohun tó ti le koko jù tí kò sì bágbà mu mọ́. Ṣé ó dá ẹ lójú pé tó o bá ń tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà, ó máa ṣe ẹ́ láǹfààní?—Ais 48:17, 18; Ro 12:2.

    Apá kan nínú fídíò “Jẹ́ Kí Ohun Tó O Gbà Gbọ́ Dá Ẹ Lójú​—Ṣé Ìlànà Ọlọ́run Ni Màá Tẹ̀ Lé àbí Èrò Ara Mi.” Hugo àti Clara.
  • Kí nìdí tí kò fi yẹ ká fara mọ́ àwọn ìwà tí ayé ń gbé lárugẹ? (Jer 10:23; 17:9; 2Kọ 11:13-15; Ef 4:18, 19)

  • Àwòrán: Àwọn àwòrán tó wà nínú fídíò “Jẹ́ Kí Ohun Tó O Gbà Gbọ́ Dá Ẹ Lójú​—Ṣé Ìlànà Ọlọ́run Ni Màá Tẹ̀ Lé àbí Èrò Ara Mi.” 1. Àmì jw.org wà lójú fóònù kan. 2. Hugo ń ka Bíbélì lórí fóònù rẹ̀ nínú ọkọ̀ èrò. 3. Clara ń gbàdúrà.
  • Kí nìdí tó fi yẹ ká fara mọ́ àwọn ìlànà tí Jèhófà fún wa? (Jo 3:16; Ro 11:33; Tit 1:2)

Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé àwọn tí kò tẹ̀ lé ìlànà Ọlọ́run “kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.” (1Kọ 6:9, 10) Àmọ́, ṣé torí àtijogún Ìjọba Ọlọ́run nìkan ló fi yẹ ká máa tẹ̀ lé ìlànà Ọlọ́run?

Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ Jẹ́ Kí Ohun Tó O Gbà Gbọ́ Dá Ẹ Lójú—Ṣé Ìlànà Ọlọ́run Ni Màá Tẹ̀ Lé àbí Èrò Ara Mi. Lẹ́yìn náà béèrè pé:

  • Báwo làwọn ìlànà Jèhófà ṣe ń dáàbò bò wá?

8. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(5 min.)

9. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 15 ¶15-20

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 133 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́