ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 November ojú ìwé 8
  • December 2-8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 2-8
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 November ojú ìwé 8

DECEMBER 2-8

SÁÀMÙ 113-118

Orin 127 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Kí La Máa San Pa Dà fún Jèhófà?

(10 min.)

Jèhófà ń dáàbò bò wá, ó ń fi inúure hàn sí wa, ó sì máa ń gbà wá (Sm 116:6-8; w01 1/1 11 ¶13)

A lè fi hàn pé a mọrírì ohun tí Jèhófà ń ṣe fún wa tá a bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, tá a sì ń fi ìlànà ẹ̀ sílò nígbèésí ayé wa (Sm 116:12, 14; w09 7/15 29 ¶4-5)

A tún lè san oore Jèhófà tá a bá ń “rú ẹbọ ọpẹ́” sí i (Sm 116:17; w19.11 22-23 ¶9-11)

Tọkọtaya kan ń wo ọ̀ọ́kán. Àwòrán: Onírúurú ọ̀nà tí wọ́n lè gbà lo àkókò wọn. 1. Wọ́n ń wo fí ìmù tí ò dáa; wọ́n jọ ń kẹ́kọ̀ọ́. 2. Wọ́n lọ sọ́jà lọ ra ọ̀pọ̀ nǹkan; wọ́n ń wàásù níbi àtẹ ìwé.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 116:15—Àwọn wo làwọn “ẹni ìdúróṣinṣin” Ọlọ́run tí Bíbélì yìí ń sọ? (w12 5/15 22 ¶1-2)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 116:1–117:2 (th ẹ̀kọ́ 2)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Má Bẹ̀rù Láti Sọ Òótọ́ Ọ̀rọ̀—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 12 kókó 1-2.

5. Má Bẹ̀rù Láti Sọ Òótọ́ Ọ̀rọ̀—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 12 kókó 3-5 àti apá “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 60

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 19 ¶1-5, àwọn àpótí ojú ìwé 149-150

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 29 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́