Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ńṣe Layé Mi Túbọ̀ Ń Bà Jẹ́ Sí I
Solomone ṣí lọ sórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, ó rò pé ayé òun á dáa sí i níbẹ̀. Àmọ́ ńṣe ló bẹ̀rẹ̀ sí í lo oògùn nílòkulò, ó sì dèrò ẹ̀wọ̀n. Kí ló ràn án lọ́wọ́ láti yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí NÍPA WA > ÌRÍRÍ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kí Nìdí Táwọn Ẹgbẹ́ Mi Ò Fi Gba Tèmi?
Èwo ló dáa jù nínú káwọn tí ìwà wọn ò dáa gba tìẹ àti pé kó o jẹ́ káwọn èèyàn mọ irú ẹni tó o jẹ́ gan an?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.