ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb25 January ojú ìwé 4
  • January 13-19

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 13-19
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
mwb25 January ojú ìwé 4

JANUARY 13-19

SÁÀMÙ 135-137

Orin 2 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Mósè na ọ̀pá ọwọ́ rẹ̀, ó fi pín Òkun Pupa. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ọ̀pọ̀ àwọn tí kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì rí ohun tó ṣẹlẹ̀, ó sì yà wọ́n lẹ́nu.

1. “Olúwa Wa Ju Gbogbo Ọlọ́run Yòókù Lọ”

(10 min.)

Jèhófà ti fi hàn pé òun láṣẹ lórí gbogbo ohun tóun dá (Sm 135:5, 6; it-2 661 ¶4-5)

Ó máa ń gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀ (Ẹk 14:29-31; Sm 135:14)

Ó máa ń ràn wá lọ́wọ́ tá a bá rẹ̀wẹ̀sì (Sm 136:23; w21.11 6 ¶16)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 135:1, 5—Kí nìdí tí Bíbélì fi sábà máa ń lo ọ̀rọ̀ náà “Jáà”? (it-1 1248)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 135:1-21 (th ẹ̀kọ́ 11)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Gba nọ́ńbà ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sọ́rọ̀ ẹ. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 4)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ DÉ ILÉ. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 4)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(5 min.) Àṣefihàn. ijwfq àpilẹ̀kọ 7—Àkòrí: Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà? (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 10

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 21 ¶1-7, àpótí ojú ìwé 166

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 90 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́