ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb25 March ojú ìwé 10
  • April 7-13

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 7-13
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
mwb25 March ojú ìwé 10

APRIL 7-13

ÒWE 8

Orin 89 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jésù ń kọ́ àwọn èèyàn níta.

1. Fetí sí Ọgbọ́n Jésù

(10 min.)

Jèhófà dá Jésù “gẹ́gẹ́ bí ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀nà rẹ̀,” òun sì ni ọgbọ́n Ọlọ́run (Owe 8:1, 4, 22; cf 131 ¶7)

Torí pé ọ̀pọ̀ ọdún ni Jésù fi wà pẹ̀lú Bàbá ẹ̀ nígbà tó ń dá àwọn nǹkan, ọgbọ́n rẹ̀ àti ìfẹ́ tó ní sí Bàbá ẹ̀ pọ̀ gan-an (Owe 8:30, 31; cf 131-132 ¶8-9)

A máa jàǹfààní tá a bá ń tẹ́tí sí ọgbọ́n Jésù (Owe 8:32, 35; w09 4/15 31 ¶14)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Owe 8:1-3—Báwo ni ọgbọ́n ṣe “ń ké tantan”? (g 7/14 16)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Owe 8:22-36 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Ẹni náà sọ pé ó ṣeé ṣe kóun wá sí Ìrántí Ikú Kristi, ó sì béèrè àwọn nǹkan tó máa ṣẹlẹ̀ níbẹ̀. Dáhùn àwọn ìbéèrè ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)

5. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Ẹnì kan rí ìwé tá a fi ń pe àwọn èèyàn wá sí Ìrántí Ikú Kristi ní ẹnu ọ̀nà ẹ̀, ó sì wá. Kí ẹni náà dáadáa kí ìpàdé tó bẹ̀rẹ̀, kó o sì dáhùn ìbéèrè tó bá ní lẹ́yìn ìpàdé náà. (lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 5)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(5 min.) Àsọyé. ijwbq àpilẹ̀kọ 160—Àkòrí: Kí Nìdí Tí A Fi Pe Jésù Ní Ọmọ Ọlọ́run? (th ẹ̀kọ́ 1)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 105

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 25 ¶1-4, àpótí ojú ìwé 199

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 7 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́