MARCH 31–APRIL 6
ÒWE 7
Orin 34 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Yẹra Fáwọn Ipò Tó O Ti Lè Kó sí Ìdẹwò
(10 min.)
Ọ̀dọ́kùnrin kan tó jẹ́ aláìmọ̀kan mọ̀ọ́mọ̀ gba àdúgbò táwọn aṣẹ́wó wà kọjá (Owe 7:7-9; w00 11/15 29 ¶5)
Aṣẹ́wó kan wá pàdé ẹ̀, ó sì fa ojú ọ̀dọ́kùnrin náà mọ́ra (Owe 7:10, 13-21; w00 11/15 30 ¶4-6)
Ó jìyà àbájáde ìpinnu tó ṣe (Owe 7:22, 23; w00 11/15 31 ¶1)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Owe 7:3—Kí ló túmọ̀ sí láti so àwọn àṣẹ Ọlọ́run mọ́ ìka wa, ká sì kọ wọ́n sí wàláà ọkàn wa? (w00 11/15 29 ¶1)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Owe 7:6-20 (th ẹ̀kọ́ 2)
4. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Nígbà tó o dé ọ̀dọ̀ ẹni náà kẹ́yìn, ó fetí sọ́rọ̀ ẹ, ó sì gba ìwé tá a fi ń pe àwọn èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 5)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Nígbà tẹ́ ẹ sọ̀rọ̀ kẹ́yìn, ẹni náà fetí sọ́rọ̀ ẹ, ó sì gba ìwé tá a fi ń pe àwọn èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 4)
6. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Nígbà tẹ́ ẹ sọ̀rọ̀ kẹ́yìn, ẹni náà fetí sọ́rọ̀ ẹ, ó sì gba ìwé tá a fi ń pe àwọn èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)
Orin 13
7. Ìgbà Míì Tó Wọ̀ (Lk 4:6)
(15 min.) Ìjíròrò.
Jẹ́ káwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:
Báwo ni Sátánì ṣe dán Jésù wò, ọ̀nà wo ló sì lè gbà dán àwa náà wò bíi ti Jésù?
Kí la lè ṣe láti borí ìdẹwò Sátánì?
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 24 ¶13-21