ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb25 July ojú ìwé 10
  • August 4-10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 4-10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2025
mwb25 July ojú ìwé 10

AUGUST 4-10

ÒWE 25

Orin 154 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jésù mú àkájọ ìwé kan dání bó ṣe ń sọ̀rọ̀ nínú sínágọ́gù. Àwọn èèyàn lọ́kùnrin, lóbìnrin títí kan àwọn ọmọdé ń tẹ́tí sí i.

Jésù ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ ní sínágọ́gù tó wà ní Násárẹ́tì, ẹnu sì ń ya àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe ń gbọ́ ọ̀rọ̀ tútù tó ń sọ

1. Àwọn Ìlànà Tó Kan Ọ̀rọ̀ Ẹnu Wa

(10 min.)

Mọ ìgbà tó yẹ kó o sọ̀rọ̀ (Owe 25:11; w15 12/15 19 ¶6-7)

Máa sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́, kó o sì máa sọ̀rọ̀ lọ́nà tó ń tuni lára (Owe 25:15; w15 12/15 21 ¶15-16; wo àwòrán)

Máa sọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró (Owe 25:25; w95 4/1 17 ¶8)

Ọ̀dọ́bìnrin kan ń bá olùkọ́ ẹ̀ sọ̀rọ̀ tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Owe 25:28—Kí ni òwe yìí túmọ̀ sí? (g19.3 6 ¶3)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Owe 25:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Bá ẹnì kan tí inú ẹ̀ ò dùn sọ̀rọ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 3)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Ẹni náà sọ pé òun lẹ́sìn tòun, òun ò sì lè fi í lẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 8 kókó 4)

6. Àsọyé

(5 min.) yp2 105-109—Àkòrí: Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Sọ̀rọ̀ Ẹlòmíì Lẹ́yìn? (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 123

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 6, ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún apá 3, àti ẹ̀kọ́ 7

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 150 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́