Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
“Mi Ò Ní Fi Ìwà Títọ́ Mi Sílẹ̀!”
Báwo ni ìtàn Jóòbù tó wà nínú Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ ká lè kojú ìṣòro àti àjálù tàbí àwọn àdánwò ìgbàgbọ́ míì?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÀGBỌ́ NÍNÚ ỌLỌ́RUN > TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Ajá Ṣe Ń Gbóòórùn
Kí ló ṣàrà ọ̀tọ̀ nínú bí ajá ṣe máa ń gbóòórùn nǹkan táwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì fi ń gbìyànjú àtimáa ṣe àwọn èrọ tó lè ṣe nǹkan tí ajá ń ṣe yìí?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?