Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
APRIL 2020
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JUNE 1–JULY 5, 2020
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Arákùnrin J. F. Rutherford àtàwọn ẹni àmì òróró míì múpò iwájú nígbà yẹn bí wọ́n ṣe ń fìgboyà kéde ìdájọ́ Jèhófà lórí ayé burúkú yìí (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 14, ìpínrọ̀ 8)