Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bí A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọmọ Lọ́wọ́ Láti Borí Ìjákulẹ̀
Gbogbo èèyàn ló máa ń ní ìjákulẹ̀. Kọ́ àwọn ọmọ rẹ láti fojú tó tọ́ wo ìjákulẹ̀, kó o sì ràn wọ́n lọ́wọ́ láti rí ojútùú.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ > ỌMỌ TÍTỌ́.
ÌRÍRÍ
Kí ló jẹ́ kí àwọn ọ̀dọ́ márùn-ún pinnu láti fara da òtútù àti òjò yìnyín kí wọ́n lè ran aládùúgbò wọn kan lọ́wọ́?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí NÍPA WA > ÌRÍRÍ > WỌ́N Ń KỌ́NI NÍ ÒTÍTỌ́ BÍBÉLÌ.