Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
July 2020
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 31–SEPTEMBER 27, 2020
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Dáfídì ò bẹ̀rù láti bá Gòláyátì jà bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọmọdé ni, kò sì lágbára. Ó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà torí ó mọ̀ pé Jèhófà máa fún òun lágbára láti ṣẹ́gun Gòláyátì, Jèhófà ò sì já a kulẹ̀ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 29, ìpínrọ̀ 11)