Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Wo ohun tó jẹ́ kí Israel Martínez lè borí èrò tó ti gbà á lọ́kàn pé òun ò já mọ́ nǹkan kan, tó sì wá dẹni tó níyì.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí NÍPA WA > ÌRÍRÍ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Èrò Tí Kò Tọ́?
Wàá rí bó o ṣe lè ní èrò tó tọ́ tó o bá fi àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí sílò.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.