Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
DECEMBER 2020
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: FEBRUARY 1-28, 2021
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Ìdílé kan tó ń gbé ní ilẹ̀ tí wọ́n ti fòfin de iṣẹ́ wa ń jọ́sìn Jèhófà nìṣó torí ó dá wọn lójú pé Jèhófà máa san wọ́n lẹ́san lọ́jọ́ iwájú (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 50, ìpínrọ̀ 4)