Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ
Nígbà tí ọkùnrin kan wà lẹ́wọ̀n ní Eritrea, ó fojú ara rẹ̀ rí bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń fi ohun tí wọ́n ń kọ́ àwọn èèyàn sílò.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí NÍPA WA > ÌRÍRÍ > WỌ́N JẸ́ OLÓÒÓTỌ́ NÍGBÀ ÀDÁNWÒ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Kò Fi Ní Máa Rẹ̀ Mí Jù?
Ṣé ó máa ń rẹ̀ ẹ́ jù? Mọ ohun tó ń fà á àti ohun tó o lè ṣe nípa ẹ̀.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.