Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí A Ṣe Lè Tọ́jú Àwọn Òbí Wa Tó Ti Dàgbà?
Àwọn ìlànà wà nínú Bíbélì tó lè ran àwọn tó ń tọ́jú àwọn àgbàlagbà lọ́wọ́.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ > ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÌWÀ RERE.
ÌRÍRÍ
Àwùjọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mẹ́tàlá (13) kan rìnrìn àjò lọ sí agbègbè Amazon tó wà ní South America kí wọ́n lè wàásù fáwọn èèyàn ibẹ̀, kí wọ́n sì jẹ́ kí wọ́n mọ̀ nípa ìrètí ọjọ́ iwájú tó wà nínú Bíbélì.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ > WỌ́N Ń KỌ́NI NÍ ÒTÍTỌ́ BÍBÉLÌ.