Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
FEBRUARY 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: APRIL 5–MAY 2, 2021
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Lẹ́yìn tí Ábígẹ́lì kó oúnjẹ ránṣẹ́ sí Dáfídì àtàwọn ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀, òun fúnra rẹ̀ wá síwájú Dáfídì. Lẹ́yìn náà, ó kúnlẹ̀, ó sì dojú bolẹ̀, ó bẹ̀ ẹ́ pé kó má gbẹ̀san torí pé ìyẹn lè mú kó jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 6, ìpínrọ̀ 16)