Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MARCH 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MAY 3–JUNE 6, 2021
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Dáfídì ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe láti dáàbò bo àwọn àgùntàn bàbá rẹ̀, kódà ó pa bíárì kan tó fẹ́ gbé àgùntàn lọ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 9, ìpínrọ̀ 4)