Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
“Mi Ò Kì Í Ṣe Ẹrú Ìwà Ipá Mọ́”
Lọ́jọ́ àkọ́kọ́ tí Michael Kuenzle bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́, ẹnì kan bi í pé: “Ṣé o rò pé Ọlọ́run ló lẹ̀bi ìyà tó ń jẹ aráyé?” Ọjọ́ yẹn layé ẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í lójútùú.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Nǹkan Bá Tojú Sú Mi?
Ṣé lílo ẹ̀rọ ìgbàlódé máa ṣèrànwọ́? Ṣé èrò tó o ní nípa ara ẹ ṣe pàtàkì?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.