Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
MAY 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JULY 5–AUGUST 1, 2021
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Lẹ́yìn tí Jésù pa dà sọ́run, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ fìtara wàásù ní Jerúsálẹ́mù àtàwọn agbègbè míì (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 20, ìpínrọ̀ 1)