Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Àwọn Obìnrin inú Bíbélì—Kí La Rí Kọ́ Lára Wọn?
Wo ìyàtọ̀ tó wà láàárín àwọn obìnrin rere tí Bíbélì mẹ́nu kàn àtàwọn obìnrin búburú tó ṣe ohun tí kò dáa.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ > BÍBÉLÌ.
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
À Ń Ṣèpàdé Látorí Ẹ̀rọ Ayélujára
Báwo ni ètò Ọlọ́run ṣe ran àwọn ìjọ lọ́wọ́ kí wọ́n lè ní ètò ìṣiṣẹ́ Zoom tí wọ́n á fi máa ṣèpàdé lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.