Eda To Wa fun Ikekoo
JUNE 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 2-29, 2021
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Arákùnrin kan àtìyàwó ẹ̀ ń fi ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! kọ́ ọkùnrin kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 22, ìpínrọ̀ 2)