Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Ẹ̀rọ Ìgbàlódé Gbà Ẹ́ Lọ́kàn
Bó o ṣe ń lo ẹ̀rọ ìgbàlódé lè ṣe ìgbéyàwó rẹ láǹfààní tàbí kó ṣàkóbá fún un. Kí ló ń ṣe fún ìgbéyàwó rẹ?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ.
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
À Ń Ran Àwọn Èèyàn Kárí Ayé Lọ́wọ́ Láti Mọ̀ọ́kọ Mọ̀ọ́kà
Àwọn aláṣẹ ní onírúurú orílẹ̀-èdè ti gbóríyìn fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà torí iṣẹ́ tí wọ́n ti ṣe láti mú káwọn èèyàn mọ̀ọ́kọ mọ̀ọ́kà.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA.