Eda To Wa fun Ikekoo
JULY 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 30–SEPTEMBER 26, 2021
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ gan-an torí pé kì í gbéra ga. Òun náà sì gbádùn kó máa wà pẹ̀lú wọn (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 29, ìpínrọ̀ 12)