Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Báwo ni ọ̀gá oníṣòwò kan tó rí tajé ṣe ṣe rí ohun kan tó túbọ̀ níye lórí ju ọrọ̀ àti owó lọ?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Kò sọ́gbọ́n kí ìṣòro má wà. Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé yálà ìṣòro tó ń bá ẹ fínra kéré tàbí ó pọ̀, ó yẹ kó o ní ìforítì.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.