Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
AUGUST 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: SEPTEMBER 27–OCTOBER 31, 2021
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Tọkọtaya kan ń wàásù níbi tí àìní gbé pọ̀; arábìnrin kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ ń yọ̀ǹda ara ẹ̀ níbi tí wọ́n ti ń kọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba; tọkọtaya àgbàlagbà kan ń wàásù látorí fóònù. Gbogbo wọn ń láyọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wọn (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 34, ìpínrọ̀ 11)