Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
OCTOBER 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: DECEMBER 6, 2021–JANUARY 2, 2022
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ ọdún ni Nóà fi wàásù, kò sẹ́ni tó fetí sí i débi tí wọ́n á fi wọnú ọkọ̀ áàkì àyàfi ìdílé rẹ̀ nìkan. Láìka èyí sí, Nóà ṣègbọràn sí Ọlọ́run! (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 43, ìpínrọ̀ 11)