Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Níbì Kan Ń Dí Àìtó Àwọn Míì
Báwo la ṣe ń rówó tá a fi ń bójú tó ohun tá a nílò láwọn ilẹ̀ tí nǹkan ò ti fi bẹ́ẹ̀ rọ̀ṣọ̀mù?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kọ́ Béèyàn Ṣe Ń Pọkàn Pọ̀?
A máa rí apá mẹ́ta tó ṣeé ṣe kí ẹ̀rọ ìgbàlódé ti dí ẹ lọ́wọ́ láti pọkàn pọ̀ àti ohun tó o lè ṣe sí i.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.