Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Ìwé Tó Ṣe Pàtàkì Jù Nínú Gbogbo Ìwé
Ohun tá à ń ṣe láti mú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde kọjá ká tú u, ká tẹ̀ ẹ́, ká sì dì í pọ̀.
Lórí JW Library, lọ sí PUBLICATIONS > ARTICLE SERIES > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
“Bí Mo Ṣe Ń Hùwà Ọ̀daràn, Tí Mo sì Lépa Owó Ṣàkóbá fún Mi”
Lẹ́yìn tí wọ́n dá Artan sílẹ̀ lẹ́wọ̀n, ó wá rí i pé òótọ́ pọ́ńbélé lohun tí Bíbélì sọ nípa ìfẹ́ owó.
Lórí JW Library, lọ sí PUBLICATIONS > ARTICLE SERIES > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.