Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
FEBRUARY 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: APRIL 4–MAY 1, 2022
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àwọn Kristẹni tó wá láti Jùdíà sá, wọ́n sọdá Odò Jọ́dánì lọ sílùú Pẹ́là. Àwọn tó kọ́kọ́ débẹ̀ ń pín oúnjẹ fáwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé (Wo àpilẹ̀kọ 9, ìpínrọ̀ 13)