Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 6: April 4-10, 2022
2 Ṣé O Gbà Pé Ohun Tó Tọ́ Ni Jèhófà Máa Ń Ṣe?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 7: April 11-17, 2022
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 8: April 18-24, 2022
14 Ṣé Bó O Ṣe Ń Gba Àwọn Èèyàn Nímọ̀ràn ‘Máa Ń Mú Ọkàn Wọn Yọ̀?’
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 9: April 25, 2022–May 1, 2022
20 Máa Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Bíi Ti Jésù
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Mo Rí Ohun Tó Dáa Ju Iṣẹ́ Dókítà Lọ
30 Ǹjẹ́ O Mọ̀?—Kí nìdí táwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́ fi máa ń san owó orí ìyàwó?
31 Ǹjẹ́ O Mọ̀?—Kí nìdí tí Jèhófà fi gbà káwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa fi ẹyẹ oriri àti ẹyẹlé rúbọ?