Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Ilé Ìwòsàn Tó Ń Fara Da Àárẹ̀
Báwo làwọn nọ́ọ̀sì àtàwọn òṣìṣẹ́ míì nílé ìwòsàn kan ṣe rí ìṣírí gbà nígbà àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19?
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Ṣó Di Dandan Kéèyàn Púpọ̀ Mọ̀ Mí Lórí Ìkànnì Àjọlò?
Àwọn kan máa ń fi ẹ̀mí wọn wewu káwọn èèyàn lè mọ̀ wọ́n, kí wọ́n sì gba tiwọn. Ṣé àǹfààní kankan tiẹ̀ wà níbẹ̀?
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Ọ́fíìsì Àwọn Atúmọ̀ Èdè Ń Ṣe Ọ̀pọ̀ Láǹfààní
Ẹ wo àǹfààní tá a máa rí tí ọ́fíìsì àwọn atúmọ̀ èdè bá wà níbi tí wọ́n ti ń sọ èdè tí wọ́n ń túmọ̀.