Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JULY 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: SEPTEMBER 5–OCTOBER 2, 2022
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Bí àsọtẹ́lẹ̀ inú ìwé Dáníẹ́lì àti ìwé Ìfihàn ṣe tan mọ́ ara wọn, tí wọ́n sì ń ṣẹ jẹ́ ká mọ ibi táwọn àsọtẹ́lẹ̀ náà ṣẹ dé àtàwọn tí ò tíì ṣẹ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 28, ìpínrọ̀ 2)