Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
A Ṣètò Ìrànwọ́ Fáwọn Ará Kárí Ayé Nígbà Àjàkálẹ̀ Àrùn
Ìrànwọ́ tá a ṣe fáwọn èèyàn nígbà àjàkálẹ̀ àrùn Kòrónà wú àwọn ará wa àtàwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórí gan-an.
ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ
Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Olówó Àtàwọn Tálákà Máa Ní Nǹkan Lọ́gbọọgba?
Àwọn èèyàn ti gbìyànjú gan-an láti mú kí ọrọ̀ ajé sunwọ̀n sí i débi tó máa fi tẹ́ gbogbo èèyàn lọ́rùn, àmọ́ wọn ò rí i ṣe. Bíbélì sọ bí Ọlọ́run ṣe máa yanjú ìṣòro yìí lọ́jọ́ iwájú.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá Kìíní: Wo Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì
Tó o bá rí àpótí ìṣúra kan tó tóbi, tí ọjọ́ ẹ̀ sì ti pẹ́ gan-an, ṣé wàá fẹ́ mọ ohun tó wà nínú ẹ̀? A lè fi Bíbélì wé irú àpótí ìṣúra yẹn torí ọ̀pọ̀ ohun iyebíye ló wà nínú ẹ̀.