Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
OCTOBER 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: DECEMBER 5, 2022–JANUARY 1, 2023
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Díẹ̀ lára àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa tó nígboyà tí wọ́n ti wà lẹ́wọ̀n tipẹ́ àtàwọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ fi sẹ́wọ̀n nítorí ohun tí wọ́n gbà gbọ́ (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 42, ìpínrọ̀ 1-2)