Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
NOVEMBER 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JANUARY 2-29, 2023
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Ìsíkíẹ́lì rí ìran kan nípa kẹ̀kẹ́ ẹṣin òkè ọ̀run, ìran yẹn sì jẹ́ kó túbọ̀ dá a lójú pé Jèhófà máa ran òun lọ́wọ́ láti jíṣẹ́ tó rán òun (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 45, ìpínrọ̀ 7)