ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w23 January ojú ìwé 32
  • Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Kọ̀ Láti Gba Àwọn Ìtàn Èké”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1994
  • Ìtàn Ìgbésí Ayé Nínú Àwọn Ìwé Ìròyìn Wa
    Ìtàn Ìgbésí Ayé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Túbọ̀ Fọkàn Tán Jèhófà àti Ètò Ẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
w23 January ojú ìwé 32

Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́

Ṣé o fẹ́ràn láti máa ka ìtàn ìgbésí ayé àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa?

Tọkọtaya kan tó máa ń ka ìtàn ìgbésí ayé ẹyọ kan láràárọ̀ sọ pé: “Àwọn ìtàn yìí máa ń fún wa níṣìírí, wọ́n sì máa ń jẹ́ ká láyọ̀! Àwọn ìtàn náà máa ń jẹ́ ká mọ̀ pé àwa náà lè jẹ́ olóòótọ́ nínú ipò èyíkéyìí tá a bá wà.” Bọ́rọ̀ ṣe rí lára arábìnrin kan nìyẹn, ó sọ pé: “Àwọn ìtàn ìgbésí ayé tí mò ń kà máa ń tù mí nínú, ó ń mórí mi yá, ó sì máa ń mọ́kàn mi yọ̀. Ohun tó dáa làwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa ń fi ìgbésí ayé wọn ṣe. Ìtàn wọn ń mú kí n ṣe púpọ̀ sí i nínú iṣẹ́ ìsìn Jèhófà, ó sì ti jẹ́ kí n ran àwọn ọmọ mi lọ́wọ́ kí wọ́n lè fi ìgbésí ayé wọn ṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún.”

Ìtàn ìgbésí ayé máa jẹ́ kó o fi ìgbésí ayé ẹ sin Jèhófà. Ó máa jẹ́ kó o borí ìrẹ̀wẹ̀sì, ó máa jẹ́ kó o lè fara da ìṣòro tó le gan-an, kó o sì máa láyọ̀. Àmọ́, ibo lo ti máa rí àwọn ìtàn náà?

  • Wo ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ náà “Ìtàn Ìgbésí Ayé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà” lórí ìkànnì jw.org tàbí nínú JW Library®.

  • Wá “Ìtàn Ìgbésí Ayé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà” lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ™ ti Watchtower tàbí Watchtower Library.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́