Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JUNE 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 14–SEPTEMBER 10, 2023
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Nígbà tí Jèhófà ní kí Gídíónì dín iye ọmọ ogun tó wà pẹ̀lú ẹ̀ kù, ó ṣe bẹ́ẹ̀. Àwọn ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin tó fi hàn pé àwọn wà lójúfò nìkan ló yàn (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 25, ìpínrọ̀ 9)