ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w23 May ojú ìwé 32
  • Ohun Tó O Lè Fi Ṣèwádìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó O Lè Fi Ṣèwádìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ohun Tá A Lè Fi Ṣèwádìí Lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ™ ti Watchtower
  • Ìwé Ìwádìí Tuntun
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ìkànnì Wa Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì—Máa Fi Ṣe Ìdákẹ́kọ̀ọ́ àti Ìjọsìn Ìdílé
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
  • Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Ṣọ̀rẹ́ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì?
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
w23 May ojú ìwé 32

Ohun Tó o Lè Fi Ṣèwádìí

Àwọn Ohun Tá A Lè Fi Ṣèwádìí Lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ™ ti Watchtower

Àwọn ohun tá a fi ń ṣèwádìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti kọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan nínú Bíbélì. Àwọn ohun tá a fi ń ṣèwádìí yìí ni, Àlàyé Ọ̀rọ̀ inú Bíbélì, Insight on the Scriptures àti Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Àpótí tá a fi ń wá nǹkan lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower máa jẹ́ kó o lè lo àwọn ìwé tá a fi ń ṣèwádìí. Tó o bá ti ń tẹ ọ̀rọ̀ sínú àpótí tá a fi ń wá nǹkan, ó máa gbé àwọn àbá mélòó kan jáde fún ẹ nísàlẹ̀ àpótí náà. Ọ̀rọ̀ náà “Topic” máa jáde lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn àbá náà.

Fi dánra wò: Bẹ̀rẹ̀ sí í tẹ ọ̀rọ̀ náà “Jèhófà” sí àpótí tá a pè ní (A). Tẹ ọ̀rọ̀ náà “Jèhófà” tó jáde nísàlẹ̀ àpótí (B) tá a kọ “Topic” sí lápá ọ̀tún. Wàá rí àwọn ohun tó o lè fi ṣèwádìí tó bá ohun tó ò ń wá mu.

Àpótí tá a fi ń wá nǹkan lórí “ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower.” Àpótí A tó wà lókè ni wọ́n ń tẹ ọ̀rọ̀ tí wọ́n fẹ́ wá sí. Àpótí B ló wà nísàlẹ̀, ọ̀rọ̀ náà “Topic” sì wà lápá ọ̀tún àwọn ọ̀rọ̀ tá à ń wá.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́