ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yb15 ojú ìwé 42-ojú ìwé 43 ìpínrọ̀ 1
  • ‘A Ti Ri Awon Ohun Agbayanu’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘A Ti Ri Awon Ohun Agbayanu’
  • Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?
    Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?
  • “Ẹrú” Tí ó Jẹ́ Olóòótọ́ Àti Olóye
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • “Ní Ti Tòótọ́, Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ Àti Olóye?”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Wọ́n “Ń Tọ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Náà Lẹ́yìn Ṣáá”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
Àwọn Míì
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
yb15 ojú ìwé 42-ojú ìwé 43 ìpínrọ̀ 1
Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 42

ÀWỌN OHUN PÀTÀKÌ TÓ ṢẸLẸ̀ LỌ́DÚN TÓ KỌJÁ

‘A Ti Rí Àwọn Ohun Àgbàyanu’

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 43

Arákùnrin kan tó jẹ́ afọ́jú ṣèrìbọmi

NÍ ÌGBÀ kan tí Jésù wo ọkùnrin kan tó jẹ́ arọ sàn, “ayọ̀ púpọ̀ jọjọ kún inú gbogbo wọn lẹ́nì kọ̀ọ̀kan, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí yin Ọlọ́run lógo, wọ́n sì kún fún ìbẹ̀rù, wọ́n wí pé: ‘Àwa ti rí ohun [àgbàyanu] lónìí!’” (Lúùkù 5:25, 26) Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run ń gbé ṣe lónìí nípasẹ̀ Ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n, ẹrú olóòótọ́ àti olóye àtàwọn olùjọsìn rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ olóòótọ́ jákèjádò ayé mú ká ní ìdí tó túbọ̀ pọ̀ sí i láti sọ ní àsọtúnsọ pé: ‘A ti rí àwọn ohun àgbàyanu.’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́