ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 1772-1773
  • B5 Àgọ́ Ìjọsìn àti Àlùfáà Àgbà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • B5 Àgọ́ Ìjọsìn àti Àlùfáà Àgbà
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
B5 Àgọ́ Ìjọsìn àti Àlùfáà Àgbà

B5

Àgọ́ Ìjọsìn àti Àlùfáà Àgbà

Bíi Ti Orí Ìwé

Àwọn Ohun Tó Wà ní Àgọ́ Ìjọsìn

  1. 1 Àpótí (Ẹk 25:10-22; 26:33)

  2. 2 Aṣọ Ìdábùú (Ẹk 26:31-33)

  3. 3 Òpó fún Aṣọ Ìdábùú (Ẹk 26:31, 32)

  4. 4 Ibi Mímọ́ (Ẹk 26:33)

  5. 5 Ibi Mímọ́ Jù Lọ (Ẹk 26:33)

  6. 6 Aṣọ Tí Wọ́n Ta (Ẹk 26:36)

  7. 7 Òpó fún Aṣọ Tí Wọ́n Ta (Ẹk 26:37)

  8. 8 Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Tí Wọ́n Fi Bàbà Ṣe (Ẹk 26:37)

  9. 9 Pẹpẹ Tùràrí (Ẹk 30:1-6)

  10. 10 Tábìlì Búrẹ́dì Àfihàn (Ẹk 25:23-30; 26:35)

  11. 11 Ọ̀pá Fìtílà (Ẹk 25:31-40; 26:35)

  12. 12 Aṣọ Àgọ́ Tí Wọ́n Fi Aṣọ Ọ̀gbọ̀ Ṣe (Ẹk 26:1-6)

  13. 13 Aṣọ Àgọ́ Tí Wọ́n Fi Irun Ewúrẹ́ Ṣe (Ẹk 26:7-13)

  14. 14 Ìbòrí Tí Wọ́n Fi Awọ Àgbò Ṣe (Ẹk 26:14)

  15. 15 Ìbòrí Tí Wọ́n Fi Awọ Séálì Ṣe (Ẹk 26:14)

  16. 16 Férémù (Ẹk 26:15-18, 29)

  17. 17 Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Tí Wọ́n Fi Fàdákà Ṣe, Tó Wà Lábẹ́ Férémù (Ẹk 26:19-21)

  18. 18 Ọ̀pá Gbọọrọ (Ẹk 26:26-29)

  19. 19 Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Tí Wọ́n Fi Fàdákà Ṣe (Ẹk 26:32)

  20. 20 Bàsíà Bàbà (Ẹk 30:18-21)

  21. 21 Pẹpẹ Ẹbọ Sísun (Ẹk 27:1-8)

  22. 22 Àgbàlá (Ẹk 27:17, 18)

  23. 23 Ẹnu Ọ̀nà (Ẹk 27: 16)

  24. 24 Àwọn Aṣọ Ìdábùú Tí Wọ́n Ta (Ẹk 27:9-15)

Àlùfáà Àgbà

Ẹ́kísódù orí 28 ṣàlàyé bí aṣọ àlùfáà àgbà ní Ísírẹ́lì ṣe rí

  • Láwàní (Ẹk 28:39)

  • Àmì Mímọ́ ti Ìyàsímímọ́ (Ẹk 28:36; 29:6)

  • Òkúta Ónísì (Ẹk 28:9)

  • Ẹ̀wọ̀n (Ẹk 28:14)

  • Aṣọ Ìgbàyà Ìdájọ́ Tó Ní Òkúta Iyebíye 12 (Ẹk 28:15-21)

  • Éfódì àti Àmùrè Tí Wọ́n Hun (Ẹk 28:6, 8)

  • Aṣọ Àwọ̀lékè Aláwọ̀ Búlúù Tí Kò Lápá (Ẹk 28:31)

  • Etí Aṣọ Tí Wọ́n So Agogo àti Pómégíránétì Mọ́ Yí Ká (Ẹk 28:33-35)

  • Aṣọ Tó Ní Bátànì Igun Mẹ́rin Tí Wọ́n Fi Aṣọ Ọ̀gbọ̀ Tó Dáa Hun (Ẹk 28:39)

  • Ohun Tó Wà Nínú Àtẹ Àwọn Ọjọ́ Ìṣẹ̀lẹ̀

  • 1512 Ṣ.S.K. Wọ́n parí àgọ́ ìjọsìn

  • 1026 Ṣ.S.K. Wọ́n ya tẹ́ńpìlì sí mímọ́

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́