2 KÍRÓNÍKÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
3
4
Pẹpẹ, Òkun àti àwọn bàsíà (1-6)
Ọ̀pá fìtílà, tábìlì àti àgbàlá (7-11a)
Bí wọ́n ṣe parí àwọn ohun tó wà nínú tẹ́ńpìlì (11b-22)
5
6
7
8
Àwọn iṣẹ́ ìkọ́lé míì tí Sólómọ́nì ṣe (1-11)
Ó ṣètò bí wọ́n á ṣe máa jọ́sìn ní tẹ́ńpìlì (12-16)
Àwọn ọkọ̀ òkun Sólómọ́nì (17, 18)
9
10
11
12
13
14
15
16
17
Jèhóṣáfátì di ọba Júdà (1-6)
Wọ́n ń kọ́ àwọn èèyàn káàkiri (7-9)
Ẹgbẹ́ ológun Jèhóṣáfátì (10-19)
18
Jèhóṣáfátì dara pọ̀ mọ́ Áhábù (1-11)
Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọn ò ní ṣẹ́gun (12-27)
Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (28-34)
19
20
Àwọn orílẹ̀-èdè tó yí Júdà ká gbógun tì í (1-4)
Jèhóṣáfátì gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́ (5-13)
Ìdáhùn tí Jèhófà fún un (14-19)
Ọlọ́run gba Júdà là lọ́nà ìyanu (20-30)
Òpin ìjọba Jèhóṣáfátì (31-37)
21
Jèhórámù di ọba Júdà (1-11)
Èlíjà kọ̀wé ránṣẹ́ (12-15)
Ìgbẹ̀yìn Jèhórámù kò dáa (16-20)
22
23
24
25
Amasááyà di ọba Júdà (1-4)
Ogun ja Édómù (5-13)
Amasááyà bọ òrìṣà (14-16)
Ogun ja Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (17-24)
Ikú Amasááyà (25-28)
26
27
28
Áhásì di ọba Júdà (1-4)
Síríà àti Ísírẹ́lì ṣẹ́gun rẹ̀ (5-8)
Ódédì kìlọ̀ fún Ísírẹ́lì (9-15)
Ọlọ́run rẹ Júdà wálẹ̀ (16-19)
Áhásì bọ̀rìṣà; ikú rẹ̀ (20-27)
29
Hẹsikáyà di ọba Júdà (1, 2)
Àwọn àtúnṣe tí Hẹsikáyà ṣe (3-11)
Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (12-19)
Ó mú iṣẹ́ ìsìn tẹ́ńpìlì pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀ (20-36)
30
31
32
Senakérúbù gbógun ti Jerúsálẹ́mù (1-8)
Senakérúbù pẹ̀gàn Jèhófà (9-19)
Áńgẹ́lì pa àwọn ọmọ ogun Ásíríà (20-23)
Àìsàn tó ṣe Hẹsikáyà àti ìgbéraga rẹ̀ (24-26)
Àwọn àṣeyọrí Hẹsikáyà àti ikú rẹ̀ (27-33)
33
34
Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2)
Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (3-13)
Wọ́n rí Ìwé Òfin (14-21)
Àsọtẹ́lẹ̀ Húlídà nípa àjálù (22-28)
Jòsáyà ka ìwé náà fún àwọn èèyàn (29-33)
35
36
Jèhóáhásì di ọba Júdà (1-3)
Jèhóákímù di ọba Júdà (4-8)
Jèhóákínì di ọba Júdà (9, 10)
Sedekáyà di ọba Júdà (11-14)
Ìparun Jerúsálẹ́mù (15-21)
Àṣẹ tí Kírúsì pa pé kí wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (22, 23)