2 ÀWỌN ỌBA
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
Ọlọ́run fi ìjì gbé Èlíjà lọ sókè (1-18)
Èlíṣà wo omi Jẹ́ríkò sàn (19-22)
Àwọn bíárì pa àwọn ọmọdékùnrin tó jáde wá láti Bẹ́tẹ́lì (23-25)
3
Jèhórámù di ọba Ísírẹ́lì (1-3)
Móábù ṣọ̀tẹ̀ sí Ísírẹ́lì (4-25)
Wọ́n ṣẹ́gun Móábù (26, 27)
4
Èlíṣà sọ òróró opó kan di púpọ̀ (1-7)
Obìnrin ará Ṣúnémù ṣe àlejò (8-16)
Obìnrin kan rí ọmọ bí; ọmọ náà kú (17-31)
Èlíṣà jí ọmọ tó kú dìde (32-37)
Èlíṣà mú kí ọbẹ̀ kan ṣeé jẹ (38-41)
Èlíṣà sọ búrẹ́dì di púpọ̀ (42-44)
5
6
Èlíṣà mú kí irin àáké léfòó (1-7)
Èlíṣà àti àwọn ará Síríà (8-23)
Ojú ìránṣẹ́ Èlíṣà là (16, 17)
Ojú inú àwọn ará Síríà fọ́ (18, 19)
Ìyàn mú ní Samáríà nígbà tí wọ́n dó tì í (24-33)
7
Èlíṣà sọ tẹ́lẹ̀ pé ìyàn máa dópin (1, 2)
Wọ́n rí oúnjẹ ní ibùdó tí àwọn ará Síríà ti sá kúrò (3-15)
Àsọtẹ́lẹ̀ Èlíṣà ṣẹ (16-20)
8
Wọ́n dá ilẹ̀ obìnrin ará Ṣúnémù pa dà fún un (1-6)
Èlíṣà, Bẹni-hádádì àti Hásáẹ́lì (7-15)
Jèhórámù di ọba Júdà (16-24)
Ahasáyà di ọba Júdà (25-29)
9
Wọ́n fòróró yan Jéhù ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì (1-13)
Jéhù pa Jèhórámù àti Ahasáyà (14-29)
Wọ́n pa Jésíbẹ́lì; àwọn ajá jẹ ẹran ara rẹ̀ (30-37)
10
Jéhù pa agbo ilé Áhábù (1-17)
Jéhù pa àwọn olùjọ́sìn Báálì (18-27)
Àkópọ̀ ìṣàkóso Jéhù (28-36)
11
Ataláyà fi ipá gba ìtẹ́ (1-3)
Wọ́n fi Jèhóáṣì jọba ní bòókẹ́lẹ́ (4-12)
Wọ́n pa Ataláyà (13-16)
Àwọn àtúnṣe tí Jèhóádà ṣe (17-21)
12
Jèhóáṣì di ọba Júdà (1-3)
Jèhóáṣì tún tẹ́ńpìlì ṣe (4-16)
Àwọn ará Síríà gbógun wá (17, 18)
Wọ́n pa Jèhóáṣì (19-21)
13
Jèhóáhásì di ọba Ísírẹ́lì (1-9)
Jèhóáṣì di ọba Ísírẹ́lì (10-13)
Èlíṣà dán ìtara Jèhóáṣì wò (14-19)
Ikú Èlíṣà; egungun rẹ̀ jí ọkùnrin kan dìde (20, 21)
Àsọtẹ́lẹ̀ tí Èlíṣà sọ kẹ́yìn ṣẹ (22-25)
14
Amasááyà di ọba Júdà (1-6)
Ó bá Édómù àti Ísírẹ́lì jà (7-14)
Ikú Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (15, 16)
Ikú Amasááyà (17-22)
Jèróbóámù Kejì di ọba Ísírẹ́lì (23-29)
15
Asaráyà di ọba Júdà (1-7)
Àwọn ọba tó jẹ kẹ́yìn ní Ísírẹ́lì: Sekaráyà (8-12), Ṣálúmù (13-16), Ménáhémù (17-22), Pekaháyà (23-26), Pékà (27-31)
Jótámù di ọba Júdà (32-38)
16
17
Hóṣéà di ọba Ísírẹ́lì (1-4)
Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (5, 6)
Ísírẹ́lì lọ sí ìgbèkùn nítorí pé ó di apẹ̀yìndà (7-23)
Wọ́n kó àwọn àjèjì wá sí àwọn ìlú Samáríà (24-26)
Àwọn ará Samáríà ń ṣe oríṣiríṣi ẹ̀sìn (27-41)
18
Hẹsikáyà di ọba Júdà (1-8)
Bí wọ́n ṣe ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (9-12)
Senakérúbù wá gbéjà ko Júdà (13-18)
Rábúṣákè pẹ̀gàn Jèhófà (19-37)
19
Hẹsikáyà wá ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run lọ́dọ̀ Àìsáyà (1-7)
Senakérúbù halẹ̀ mọ́ Jerúsálẹ́mù (8-13)
Àdúrà Hẹsikáyà (14-19)
Àìsáyà sọ ìdáhùn Ọlọ́run fún un (20-34)
Áńgẹ́lì pa 185,000 àwọn ará Ásíríà (35-37)
20
21
22
Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2)
Bí wọ́n ṣe máa tún tẹ́ńpìlì ṣe (3-7)
Wọ́n rí ìwé Òfin (8-13)
Húlídà sọ tẹ́lẹ̀ pé àjálù máa ṣẹlẹ̀ (14-20)
23
Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (1-20)
Wọ́n ṣe Ìrékọjá (21-23)
Àwọn àtúnṣe míì tí Jòsáyà ṣe (24-27)
Ikú Jòsáyà (28-30)
Jèhóáhásì di ọba Júdà (31-33)
Jèhóákímù di ọba Júdà (34-37)
24
Jèhóákímù ṣọ̀tẹ̀, ó sì kú (1-7)
Jèhóákínì di ọba Júdà (8, 9)
Ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì (10-17)
Sedekáyà di ọba Júdà; ó ṣọ̀tẹ̀ (18-20)
25
Nebukadinésárì dó ti Jerúsálẹ́mù (1-7)
Ìparun Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀; wọ́n kó wọn lọ nígbà kejì (8-21)
Wọ́n fi Gẹdaláyà ṣe gómìnà (22-24)
Wọ́n pa Gẹdaláyà; àwọn èèyàn sá lọ sí Íjíbítì (25, 26)
Wọ́n tú Jèhóákínì sílẹ̀ ní Bábílónì (27-30)