Ẹ́SÍRÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
2
3
Wọ́n tún pẹpẹ kọ́, wọ́n sì rú àwọn ẹbọ (1-6)
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í tún tẹ́ńpìlì kọ́ (7-9)
Wọ́n fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì lélẹ̀ (10-13)
4
Wọ́n gbógun ti iṣẹ́ títún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-6)
Àwọn ọ̀tá fi ìwé ẹ̀sùn ránṣẹ́ sí Ọba Atasásítà (7-16)
Ìdáhùn Atasásítà (17-22)
Iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì dáwọ́ dúró (23-24)
5
6
7
Ẹ́sírà wá sí Jerúsálẹ́mù (1-10)
Lẹ́tà tí Atasásítà kọ sí Ẹ́sírà (11-26)
Ẹ́sírà yin Jèhófà (27-28)
8
Orúkọ àwọn tó tẹ̀ lé Ẹ́sírà pa dà (1-14)
Wọ́n múra ìrìn àjò náà (15-30)
Wọ́n kúrò ní Bábílónì, wọ́n dé sí Jerúsálẹ́mù (31-36)
9
10