ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 January ojú ìwé 5
  • Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ẹ́sírà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Àtẹ Àwọn Ọjọ́ Ìṣẹ̀lẹ̀
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Hágáì àti Ìwé Sekaráyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 January ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́SÍRÀ 1-5

Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ

Bíi Ti Orí Ìwé
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù kọ́

Jèhófà ṣèlérí pé òun á mú kí àwọn èèyàn òun pa dà máa jọ́sìn òun nínú tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù. Àmọ́ ọ̀pọ̀ ìṣòro làwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó pa dà dé láti ìgbèkùn Bábílónì ní. Bí àpẹẹrẹ, ọba pàṣẹ pé kí wọ́n dáwọ́ iṣẹ́ ìkọ́lé tí wọ́n ń ṣe dúró. Torí náà ọ̀pọ̀ lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbà pé àwọn ò ní lè parí iṣẹ́ náà.

  1. nǹkan bí 537 Ṣ.S.K.

    Kírúsì pàṣẹ pé kí wọ́n lọ tún tẹ́ńpìlì kọ́

  2. 3:3

    Oṣù keje

    Wọ́n mọ pẹpẹ; wọ́n rú ẹbọ

  3. 3:​10, 11

    536 Ṣ.S.K.

    Wọ́n fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì lélẹ̀

  4. 4:​23, 24

    522 Ṣ.S.K.

    Atasásítà Ọba dá iṣẹ́ ìkọ́lé náà dúró

  5. 5:​1, 2

    520 Ṣ.S.K.

    Sekaráyà àti Hágáì gba àwọn èèyàn náà níyànjú láti pa dà sí ẹnu iṣẹ́ ìkọ́lé náà

  6. 6:15

    515 Ṣ.S.K.

    Wọ́n parí kíkọ́ tẹ́ńpìlì

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́