January Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé January 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò January 4 Sí 10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KÍRÓNÍKÀ 29-32 Ìjọsìn Tòótọ́ Gba Ìsapá MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Bí A Ṣe Lè Fi Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Darí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àǹfààní Tá A Ní Láti Kọ́ Àwọn Ibi Tí A Ti Ń Ṣe Ìjọsìn Tòótọ́ Ká sì Máa Bójú Tó Wọn January 11 Sí 17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KÍRÓNÍKÀ 33-36 Jèhófà Mọyì Ojúlówó Ìrònúpìwàdà January 18 Sí 24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́SÍRÀ 1-5 Jèhófà Máa Ń Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ January 25 Sí 31 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́SÍRÀ 6-10 Àwọn Tó Ń Fi Tinútinú Yọ̀ǹda Ara Wọn Ni Jèhófà Fẹ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Sọ Ohun Tó O Máa Bá Onílé Jíròrò Nígbà Tó O Bá Pa Dà Wá