NÁHÚMÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ọlọ́run máa gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀ (1-7) Ọlọ́run fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo (2) Jèhófà mọ àwọn tó ń wá ibi ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀ (7) Nínéfè máa pa run (8-14) Wàhálà kò ní dìde lẹ́ẹ̀kejì (9) Ìròyìn ayọ̀ fún Júdà (15) 2 Nínéfè máa pa run (1-13) “Ilẹ̀kùn àwọn odò rẹ̀ máa ṣí sílẹ̀” (6) 3 “Ìlú tó ń ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ gbé!” (1-19) Ìdí tí Ọlọ́run fi máa dá Nínéfè lẹ́jọ́ (1-7) Nínéfè máa ṣubú bíi No-ámónì (8-12) Ó dájú pé Nínéfè máa ṣubú (13-19)